Kọ́ èdè Yorùbá pẹ̀lú Olùkọ́ Akónilẹ́dè · Learn Yoruba language with Oluko Akonilede

Kọ́ èdè Yorùbá ní ìpele jìpele.

Learn Yoruba language, level by level.

Ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá tó rọrùn tí o lè kọ́ ní àkókò tó bá wù ọ́.
Friendly Yoruba language lessons you can take at your convenience.

Yan ìlànà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tó wù ọ́. Choose your preferred learning pathway.

Àwọn ọmọdéYoung children · 4–8 yearsỌmọ ọdún mẹ́rin sí ọmọ ọdún mẹ́jọ Àwọ̀, ohùn àti eréColor, sound and playÀwọn ọ̀dọ́mọdéOlder children · 8–13 yearsỌmọ ọdún mẹ́jọ sí ọmọ ọdún mẹ́tàlá Ọ̀rọ̀ àti ìtọ́sọ́nà tó munadokoVocabulary and effective guidanceÀgbà · Adults Èdè Yorùbá fún ìgbésí ayéPractical Yoruba for real life

Bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ · How it works

Ìgbésẹ̀ mẹ́ta tó rọrùn Three simple steps

Módù kọ̀ọ̀kan jẹ́ àkójọpọ̀ kíláàsì tó pé. Each module is a complete learning bundle.

01

Yan ìlànà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Choose a learning pathway

Yan kílásì fún àwọn ọmọdé, àwọn ọ̀dọ́mọdé tàbí àwọn àgbà. Select Young Children, Older Children or Adults.

02

San owó fún módù kan Pay for a module

Owó kan tí o bá san yóò fún ọ ní kóòdù láti kọ́ gbogbo ẹ̀kọ́ inú módù náà. One payment gives you a code for every lesson in that module.

03

Wò, kọ́, kí o sì mú lò Watch, learn and use it

Gbọ́, sọ tẹ̀lé, dá dúró, tún wò, kí o sì ṣe ìdánwò. Listen, repeat, pause, replay and complete the interactive checks.

Àtìlẹ́yìn òbí fún àwọn ọmọdé Parental support for children

A gba òbí tàbí alágbàtọ́ níyànjú láti ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ nígbà tí wọ́n bá ń kọ́ ẹ̀kọ́. Parents and caregivers are encouraged to support children while they learn.

Kàn sí olùkọ́ rẹ · Contact your tutor

Ṣé o ní ìbéèrè? Questions or live-class enquiries?

Contact Oluko Akonilede by email, phone, text message or WhatsApp.